The Yoruba Choir ministration assured everyone that there is still hope to every hopeless situation.
No matter the situation you are faced with, in the Lord’s Chosen today there is hope.
Below is the lyrics of their song ministration.
IRETI NBE FUN ALAINI
(Highlife)
There is sure hope for the hopeless
There is sure hope for he that has faith
There is sure hope for all mankind Jesus the hope of the needy is in our midst.
Chorus: Ireti nbe f’eni taye to ro pin
Ireti n be feni to ba ni gbagbo
Ireti n be fun gbogbo eda alaaye
Jesu ireti alaini ti was larin wa.
SOLO 1: O ti sare ka, ‘tori o fe iranlowo
O gun Petele, o tun gori oke lo
Sibesibe oro re ko ni yanju oLoni,
loni, olorun ayanfe a ba o se
SOLO 2: ko tile ye o mo, ohun ti o tun le se
Sugbon o gbo ipe, pe ko wa si’jo ayanfe
B’o ti wa yii, oro re yio si dayo
Olorun ayanfe, yoo foyin saye re
SOLO 3: Akirisore,o ti wa legbe odo re
O see l’ana, yo see tuntun loni o
Mu okan re le,ko feti si oro re
Ise iyanu meriri yoo je ipin re
SOLO 4: Alfa,Omega,Alasepe igbagbo wa
Gbogbo oore -ofe lati tele titi dopin
Yoo sokale sori gbogbo wa
Lonille-ogo yoo je ti wa nikehin
Hallelujah
Jesu ireti alaini ti wa larin wa (2X)
Click on the link to watch the full ministration:
https://www.youtube.com/watch?v=1aTRxQFRzec
#HopeForTheNeedy2021#PstLazarusMuoka#LagosExperience
Yoruba Choir #HopeForTheNeedy2021